بِسْمِ اللَّهِ، وَالْحَمْدُ للَّهِ ﴿سُبْحَانَ الَّذِي سَخَّرَ لَنَا هَذَا وَمَا كُنَّا لَهُ مُقْرِنِينَ، وَإِنَّا إِلَى رَبِّنَا لَمُنقَلِبُونَ﴾، ((الْحَمْدُ لِلَّهِ، الْحَمْدُ لِلَّهِ، الْحَمْدُ لِلَّهِ، اللَّهُ أَكْبَرُ، اللَّهُ أَكْبَرُ، اللَّهُ أَكْبَرُ، سُبْحَانَكَ اللَّهُمَّ إِنِّي ظَلَمْتُ نَفْسِي فَاغْفِرْ لِي؛ فَإِنَّهُ لاَ يَغْفِرُ الذُّنُوبَ إِلاَّ أَنْتَ
Ní orúkọ Allāhu, gbogbo ìyìn sì ni ti Allāhu.Mímọ́ ni Òun,Ẹni tí ó fi èyí (ọkọ̀ ìrìnnà) sábẹ́ wa,àwa fúnra wa kò sì ní lè ṣe bẹ́ẹ̀,àti sí Olúwa wa ni ìpadàbọ̀ wa.Gbogbo ìyìn ni ti Allāhu,Gbogbo ìyìn ni ti Allāhu,Gbogbo ìyìn ni ti Allāhu, Allāhu tóbi jùlọ,Allāhu tóbi jùlọ, Allāhu tóbi jùlọ.Mímọ́ ni Ọ́, Áà Allāhu,dájúdájú mo ti ṣe ọkàn mi ní àìṣòdodo,nítorí náà dárí jìn mí,nítorí dájúdájú kò sí ẹni tí ó lè dárí ẹ̀ṣẹ̀ jìn àyàfi Ìwọ.



