أَسْتَغْفِرُ اللَّهَ (ثَلاَثَاً) اللَّهُمَّ أَنْتَ السَّلاَمُ، وَمِنْكَ السَّلاَمُ، تَبَارَكْتَ يَا ذَا الْجَلاَلِ وَالْإِكْرَامِ
Mo tọrọ ìdáríjì lọ́dọ̀ Allāhu.(ìgbà mẹ́taÁà Allāhu, Ìwọ ni As-Salām,láti ọ̀dọ̀ Rẹ sì ni gbogbo àlàáfíà ti ń wá,ìbùkún ni fún Ọ, Áà Olúwa ọlá àti ọlọ́lá.(AS-Salām: Ẹni tí ó mọ́ kúrò nínú gbogbo àbùkù àti àìpé.))



