يَجْمَعُ كَفَّيْهِ ثُمَّ يَنْفُثُ فِيهِمَا فَيَقْرَأُ فِيهِمَا:بسم الله الرحمن الرحيم ﴿قُلْ هُوَ اللَّهُ أَحَدٌ اللَّهُ الصَّمَدُ لَمْ يَلِدْ وَلَمْ يُولَدْ وَلَمْ يَكُن لَّهُ كُفُواً أَحَدٌ﴾بسم الله الرحمن الرحيم ﴿قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ الْفَلَقِ مِن شَرِّ مَا خَلَقَ وَمِن شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ وَمِن شَرِّ النَّفَّاثَاتِ فِي الْعُقَدِ وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ﴾بسم الله الرحمن الرحيم ﴿قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ النَّاسِ مَلِكِ النَّاسِ إِلَهِ النَّاسِ مِن شَرِّ الْوَسْوَاسِ الْخَنَّاسِ الَّذِي يُوَسْوِسُ فِي صُدُورِ النَّاسِ مِنَ الْجِنَّةِ وَ النَّاسِ﴾ثُمَّ يَمْسَحُ بِهِمَا مَا اسْتَطَاعَ مِنْ جَسَدِهِ يَبْدَأُ بِهِمَا عَلَى رَأْسِهِ وَوَجْهِهِ وَمَا أَقبَلَ مِنْ جَسَدِهِيفعلُ ذلك ثلاثَ مرَّاتٍ
Nígbà tí Anọ́bì ﷺ bá dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀ ní alẹ́ kọ̀ọ̀kan,yóò kó àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ méjèèjì pọ̀,yóò tu itọ́ (ìtutọ́ onírú kan tí ó jẹ́afẹ́fẹ́ ní pàtàkì pẹ̀lú itọ́ díẹ̀) sínú wọn,yóò ka àwọn orí mẹ́ta tó kẹ́yìn (Al-Ikhlās,Al-Falaq, An-Nās) nínú Kùránì,lẹ́yìn náà yóò fi ọwọ́ rẹ̀ nu gbogbo ara rẹ̀ bí ó ti lè ṣe tó,bẹ̀rẹ̀ láti orí àti ojú rẹ̀,lẹ́yìn náà àwọn ẹ̀yà ara yòókù,yóò sì ṣe èyí ní ìgbà mẹ́ta.



