اللَّهُمَّ اجْعَلْ فِي قَلْبِي نُوراً، وَفِي لِسَانِي نُوراً، وَفِي سَمْعِي نُوراً، وَفِي بَصَرِي نُوراً، وَمِنْ فَوْقِي نُوراً، وَمِنْ تَحْتِي نُوراً، وَعَنْ يَمِينِي نُوراً، وعَنْ شِمَالِي نُوراً، وَمِنْ أَمَامِي نُوراً، وَمِنْ خَلْفِي نُوراً، واجْعَلْ فِي نَفْسِي نُوراً، وأَعْظِمْ لِي نُوراً، وَعظِّمْ لِي نُوراً، وَاجْعَلْ لِي نُوراً، واجْعَلْنِي نُوراً، اللَّهُمَّ أَعْطِنِي نُوراً، واجْعَلْ فِي عَصَبِي نُوراً، وَفِي لَحْمِي نُوراً، وَفِي دَمِي نُوراً وَفِي شَعْرِي نُوراً، وفِي بَشَرِي نُوراً (اللَّهُمَّ اجْعَلْ لِي نُوراً فِي قَبْرِي وَنُوراً فِي عِظَامِي) وَزِدْنِي نُوراً، وَزِدْنِي نُوراً، وَزِدْنِي نُوراً وَهَبْ لِي نُوراً عَلَى نُورٍ
‘Áà Allāhu,fi ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn mi; àti ìmọ́lẹ̀ sóríahọ́n mi; àti ìmọ́lẹ̀ sí etí mi; àti ìmọ́lẹ̀sí ojú mi; kí o sì fi ìmọ́lẹ̀ sí òkè mi;àti ìmọ́lẹ̀ sí abẹ́ mi; àti ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀túnmi; àti ìmọ́lẹ̀ ní òsì mi; àti ìmọ́lẹ̀ níwájúmi; àti ìmọ́lẹ̀ lẹ́yìn mi; kí o sì fi ìmọ́lẹ̀sínú ọkàn mi; kí o sì mú ìmọ́lẹ̀ pọ̀ síi fún mi; kí o sì sọ ìmọ́lẹ̀ di ńlá fúnmi; kí o sì fún mi ní ìmọ́lẹ̀ kí o sì ṣe mí ní ìmọ́lẹ̀.Áà Allāhu,fún mi ní ìmọ́lẹ̀; kí o sì fi ìmọ́lẹ̀ sínúiṣan mi; àti ìmọ́lẹ̀ nínú ẹran ara mi; àtiìmọ́lẹ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ mi; àti ìmọ́lẹ̀ nínúirun mi àti ìmọ́lẹ̀ nínú awọ ara mi.’ [Áà Allāhu,fi ìmọ́lẹ̀ sí sàréè mi fún mi àti ìmọ́lẹ̀ sínú egungun mi].[Kí o sì mú ìmọ́lẹ̀ pọ̀ sí i fún mi,kí o sì mú ìmọ́lẹ̀ pọ̀ sí i fún mi,kí o sì mú ìmọ́lẹ̀ pọ̀ sí i fún mi].[Kí o sì fún mi ní ìmọ́lẹ̀ lórí ìmọ́lẹ̀.]’



